Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Resurrection of Christ: The fulfilment of Scripture
Àwọn ẹsẹ nípa The fulfilment of Scripture
Nígbà náà ni ó ṣí wọn ní iyè, kí ìwé mímọ́ lè yé wọn.
Ó sì wí fún wọn pé, “Bẹ́ẹ̀ ni a ti kọ̀wé rẹ̀, pé: kí Kristi jìyà, àti kí ó sì jíǹde ní ọjọ́ kẹta kúrò nínú òkú,