Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Resurrection of Christ: Apostles, Thomas being present
Àwọn ẹsẹ nípa Apostles, Thomas being present
Lẹ́yìn ọjọ́ mẹ́jọ àwọn ọmọ-ẹ̀yìn sì tún wà nínú ilé, àti Tomasi pẹ̀lú wọn: nígbà tí a sì ti ti ìlẹ̀kùn, Jesu dé, ó sì dúró láàrín, ó wí pé, “Àlàáfíà fún yín.”