Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Resurrection of Christ: The power of the Holy Spirit
Àwọn ẹsẹ nípa The power of the Holy Spirit
Nítorí tí Kristi pẹ̀lú jìyà lẹ́ẹ̀kan nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wa, olóòótọ́ fún àwọn aláìṣòótọ́, kí a lè mú wa dé ọ̀dọ̀ Ọlọ́run, ẹni tí a pa nínú ara, ṣùgbọ́n tí a sọ di ààyè nínú ẹ̀mí.