Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa The Resurrection of Christ: An assurance of the judgment

1 ẹsẹ · 46 abala

Àwọn ẹsẹ nípa An assurance of the judgment

  1. Níwọ́n bí ó ti dá ọjọ́ kan, nínú èyí tí yóò ṣe ìdájọ́ ayé lódodo nípasẹ̀ ọkùnrin náà tí ó ti yàn, nígbà tí ó ti fi ohun ìdánilójú fún gbogbo ènìyàn, ní ti pé ó jí dìde kúrò nínú òkú.”