Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Shemaiah: 7. A chief Levite in time of David; assisted in moving the ark from Obed-Edom
Àwọn ẹsẹ nípa 7. A chief Levite in time of David; assisted in moving the ark from Obed-Edom
Igba nínú àwọn ọmọ Elisafani; Ṣemaiah olórí àti àwọn ẹbí rẹ̀.
Dafidi sì ránṣẹ́ pe Sadoku, Abiatari tí wọ́n jẹ́ àlùfáà, àti Urieli, Asaiah. Joẹli, Ṣemaiah, Elieli àti Amminadabu tí wọ́n jẹ́ Lefi.