Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Shemaiah: 8. A Levite who assisted in the division of the priests

1 ẹsẹ · 23 abala

Àwọn ẹsẹ nípa 8. A Levite who assisted in the division of the priests

  1. Ṣemaiah ọmọ Netaneli, akọ̀wé ọ̀kan lára àwọn ọmọ Lefi sì kọ orúkọ wọn níwájú ọba àti àwọn ìjòyè: Sadoku àlùfáà, Ahimeleki ọmọ Abiatari àti olórí ìdílé àwọn àlùfáà tí a mú láti ọ̀dọ̀ Eleasari àti ọ̀kan láti ọ̀dọ̀ Itamari.