Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Shemaiah: 18. Keeper of the East Gate of Jerusalem in the time of Nehemiah
Àwọn ẹsẹ nípa 18. Keeper of the East Gate of Jerusalem in the time of Nehemiah
Lẹ́yìn wọn, Sadoku ọmọ Immeri tún ọ̀kánkán òdìkejì ilé rẹ̀ ṣe. Lẹ́yìn rẹ̀ ni Ṣemaiah ọmọ Ṣekaniah, olùṣọ́ ibodè ìhà ìlà-oòrùn ṣe àtúnṣe.