Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Shemaiah: 24. Father of the prophet Urijah
Àwọn ẹsẹ nípa 24. Father of the prophet Urijah
(Bákan náà Uriah ọmọ Ṣemaiah láti Kiriati-Jearimu jẹ́ ọkùnrin mìíràn tí ó sọ àsọtẹ́lẹ̀ kan náà ní orúkọ Olúwa. Ó sọ àsọtẹ́lẹ̀ kan náà sí ìlú náà àti ilẹ̀ yín bí Jeremiah ti ṣe.