Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Shemaiah: 13. A Levite who contributed largely for Passover sacrifices
Àwọn ẹsẹ nípa 13. A Levite who contributed largely for Passover sacrifices
Àti pẹ̀lú Konaniah àti pẹ̀lú Ṣemaiah àti Netaneli, àti àwọn arákùnrin rẹ̀, àti Haṣabiah, Jeieli àti Josabadi olórí àwọn ọmọ Lefi, ó sì pèsè ẹgbẹ̀rún márùn-ún (5,000) ẹbọ ìrékọjá àti ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta (500) orí ẹran ọ̀sìn fún àwọn ọmọ Lefi.