Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Shemaiah: 23. The name of three men who celebrated the dedication of the new wall of Jerusalem

3 ẹsẹ · 23 abala

Àwọn ẹsẹ nípa 23. The name of three men who celebrated the dedication of the new wall of Jerusalem

  1. Juda, Benjamini, Ṣemaiah, Jeremiah,

  2. àti àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ̀, Ṣemaiah, Asareeli, Milalai, Gilalai, Maai, Netaneli, Juda àti Hanani—pẹ̀lú ohun èlò orin bí àṣẹ Dafidi ènìyàn Ọlọ́run. Esra akọ̀wé ni ó ṣáájú wọn bí wọ́n ti ń tò lọ lọ́wọ̀ọ̀wọ́.

  3. Àti pẹ̀lú Maaseiah, Ṣemaiah, Eleasari àti Ussi, àti Jehohanani, àti Malkiah, àti Elamu, àti Eseri. Àwọn akọrin kọrin sókè ní abẹ́ alábojútó Jesrahiah.