Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Sheep: Wool of, made into clothing

3 ẹsẹ · 63 abala

Wá "Sheep"

Àwọn ẹsẹ nípa Wool of, made into clothing

  1. bí ọkàn rẹ̀ kò bá súre fún mi, tàbí bí ara rẹ̀ kò sì gbóná nípasẹ̀ irun àgùntàn mi;

  2. Ó sa aṣọ irun àgùntàn olówùú àti ọ̀gbọ̀ Ó sì ṣiṣẹ́ pẹ̀lú ìyárí.

  3. Ìwọ jẹ wàrà. O sì wọ aṣọ olówùú sí ara rẹ, o sì ń pa ẹran tí ó wù ọ́, ṣùgbọ́n ìwọ kò tọ́jú agbo ẹran.