Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Sheep: (When found,) of restored sinners

2 ẹsẹ · 63 abala

Àwọn ẹsẹ nípa (When found,) of restored sinners

  1. Nígbà tí ó bá sì rí i tán, yóò gbé e lé èjìká rẹ̀ pẹ̀lú ayọ̀.

  2. Mo wí fún yín, gẹ́gẹ́ bẹ́ẹ̀ ni ayọ̀ yóò wà ní ọ̀run lórí ẹlẹ́ṣẹ̀ kan tí ó ronúpìwàdà, ju lórí olóòtítọ́ mọ́kàndínlọ́gọ́rùn-ún lọ, tí kò nílò ìrònúpìwàdà.