Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Sheep: (Separation from the goats,) of the separation of saints from the wicked

2 ẹsẹ · 63 abala

Àwọn ẹsẹ nípa (Separation from the goats,) of the separation of saints from the wicked

  1. Gbogbo orílẹ̀-èdè ni a ó kójọ níwájú rẹ̀, òun yóò sì ya àwọn ènìyàn ayé sí ọ̀tọ̀ gẹ́gẹ́ bí olùṣọ́-àgùntàn ṣe é ya àgùntàn kúrò lára àwọn ewúrẹ́.

  2. Òun yóò sì fi àgùntàn sí ọwọ́ ọ̀tún àti ewúrẹ́ sí ọwọ́ òsì.