Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Sheep: Nebaioth

1 ẹsẹ · 63 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Nebaioth

  1. Gbogbo agbo ẹran ìlú Kedari ni a ó kójọ sọ́dọ̀ rẹ, àwọn àgbò ti Nebaioti yóò sìn ọ́; wọn yóò jẹ́ ọrẹ ìtẹ́wọ́gbà lórí i pẹpẹ mi, bẹ́ẹ̀ ni n ó sì ṣe tẹmpili ògo mi lọ́ṣọ̀ọ́.