Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Serpent: The wound of, miraculously healed by looking upon the brazen serpent, set up by Moses
Àwọn ẹsẹ nípa The wound of, miraculously healed by looking upon the brazen serpent, set up by Moses
Olúwa sọ fún Mose pé, “Rọ ejò, a ó sì gbé e kọ́ sókè lórí igi, ẹni tí ejò bá ti gé jẹ lè wò ó yóò sì yè.”
Nígbà náà ni Mose sì rọ ejò onírin ó sì gbé e kọ́ sórí igi, bí ejò bá sì bu ẹnikẹ́ni jẹ bí ó bá ti wò ó yóò sì yè.