Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Serpent: The seventy endued with power over
Àwọn ẹsẹ nípa The seventy endued with power over
Kíyèsi i, èmí fún yín ní àṣẹ láti tẹ ejò àti àkéekèe mọ́lẹ̀, àti lórí gbogbo agbára ọ̀tá, kò sì ṣí ohun kan bí ó ti wù tí ó ṣe, tí yóò pa yín lára.