Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Serpent: The apostles given power over
Àwọn ẹsẹ nípa The apostles given power over
Wọn yóò sì gbé ejò lọ́wọ́, bí wọ́n bá sì jẹ májèlé kò nípa wọ́n lára rárá. Wọ́n yóò gbé ọwọ́ lé àwọn aláìsàn, ara wọn yóò sì dá.”
Òun sì gbọn ẹranko náà sínú iná ohunkóhun kan kò sì ṣe é.