Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Salutations: On entering a house
Àwọn ẹsẹ nípa On entering a house
Wọ́n sì yà sí ibẹ̀, wọ́n sì wọ ilé ọ̀dọ́mọkùnrin Lefi náà, sí ilé Mika, wọ́n sì béèrè àlàáfíà rẹ̀.
Nígbà tí ẹ̀yin bá sì wọ ilé kan, ẹ kí i wọn.
Ó sì wọ ilé Sekariah lọ ó sì kí Elisabeti.
Ó sì ṣe, nígbà tí Elisabeti gbọ́ kíkí Maria, ọlẹ̀ sọ nínú rẹ̀; Elisabeti sì kún fún Ẹ̀mí Mímọ́,
Sá wò ó, bí ohùn kíkí rẹ ti bọ́ sí mi ní etí, ọlẹ̀ sọ nínú mi fún ayọ̀.