Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Salutations: Servants to their masters, »The Lord bless thee«
Àwọn ẹsẹ nípa Servants to their masters, »The Lord bless thee«
Nígbà náà ni Boasi dé láti Bẹtilẹhẹmu tí ó sì kí àwọn olùkórè wí pé, “Kí Olúwa wà pẹ̀lú yín.” Wọ́n sì dá a lóhùn pé, “Kí Olúwa bùkún fún ọ.”