Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Salutations: By letter
Àwọn ẹsẹ nípa By letter
Ìkíni ti èmi Paulu, láti ọwọ́ èmi tìkára mi wá.
Gbogbo àwọn ènìyàn Ọlọ́run níbi kí i yín.
Ẹ kí olúkúlùkù ènìyàn mímọ́ nínú Kristi Jesu. Àwọn ará tí ó wà pẹ̀lú mi kí yín.
Ìkíni láti ọwọ́ èmi Paulu. Ẹ máa rántí ìdè mi. Kí oore-ọ̀fẹ́ kí ó wà pẹ̀lú yín.
Èmi Paulu fi ọwọ́ ara mi kọ lẹ́tà ìkíni yìí, èyí ṣe àmì ìdámọ̀ nínú gbogbo lẹ́tà. Bí mo ṣe máa ń kọ̀wé nìyìí.
Àwọn ọmọ arábìnrin rẹ àyànfẹ́ kí ọ.
Mo ni ìrètí láti rí ọ láìpẹ́, tí àwa yóò sì sọ̀rọ̀ lójúkojú.