Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Salutations: From a master to his servants, »The Lord be with you«
Àwọn ẹsẹ nípa From a master to his servants, »The Lord be with you«
Nígbà náà ni Boasi dé láti Bẹtilẹhẹmu tí ó sì kí àwọn olùkórè wí pé, “Kí Olúwa wà pẹ̀lú yín.” Wọ́n sì dá a lóhùn pé, “Kí Olúwa bùkún fún ọ.”