Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Reproof: Wisdom

2 ẹsẹ · 70 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Wisdom

  1. Ẹni tí ó fetí sí ìbáwí tí ń fún ni ní ìyè, yóò wà ní àpéjọpọ̀ àwọn ọlọ́gbọ́n.

  2. Ọ̀pá ìbániwí ń fún ni ní ọgbọ́n ṣùgbọ́n ọmọ tí a fi sílẹ̀ fúnra rẹ̀ a dójútì ìyá rẹ̀.