Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Reproof: The Holy Spirit gives

2 ẹsẹ · 70 abala

Àwọn ẹsẹ nípa The Holy Spirit gives

  1. Ṣùgbọ́n òtítọ́ ni èmi ń sọ fún yín; àǹfààní ni yóò jẹ́ fún yín bí èmi bá lọ, nítorí bí èmi kò bá lọ, Olùtùnú kì yóò tọ̀ yín wá; ṣùgbọ́n bí mo bá lọ, èmi ó rán an sí yín.

  2. Nígbà tí òun bá sì dé, yóò fi òye yé aráyé ní ti ẹ̀ṣẹ̀, àti ní ti òdodo, àti ní ti ìdájọ́,