Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Reproof: Shemaiah

1 ẹsẹ · 70 abala

Wá "Reproof"

Àwọn ẹsẹ nípa Shemaiah

  1. Nígbà náà, wòlíì Ṣemaiah wá sí ọ̀dọ̀ Rehoboamu àti sí ọ̀dọ̀ àwọn olórí Juda tí wọ́n ti péjọ ní Jerusalẹmu nítorí ìbẹ̀rù Ṣiṣaki, ó sì wí fún wọn pé, “Èyí ni ohun tí Olúwa wí: ìwọ ti pa mí tì; nítorí náà èmi náà ti pa yín tì sí ọ̀dọ̀ Ṣiṣaki.”