Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Reproof: Hypocrites not qualified to give
Àwọn ẹsẹ nípa Hypocrites not qualified to give
Ìwọ àgàbàgebè, tètè kọ́ yọ ìtì igi jáde kúrò ní ojú ara rẹ ná, nígbà náà ni ìwọ yóò sì tó ríran kedere láti yọ ẹ̀rún igi tí ń bẹ ní ojú arákùnrin rẹ kúrò.