Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Protection: Upholding them
Àwọn ẹsẹ nípa Upholding them
nítorí pé a óò ṣẹ́ ọwọ́ àwọn ènìyàn búburú, ṣùgbọ́n Olúwa gbé olódodo sókè.
bí ó tilẹ̀ ṣubú a kì yóò ta á nù pátápátá, nítorí tí Olúwa di ọwọ́ rẹ̀ mú.
Ọkàn mí fà sí ọ: ọwọ́ ọ̀tún rẹ gbé mi ró.