Sidon
A tún mọ̀ ọ́n sí: Great Sidon, Zidon
33.5600, 35.3600 Wo lórí Google Maps
Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Sidon
Olúwa sì fi wọ́n lé Israẹli lọ́wọ́. Wọ́n ṣẹ́gun wọn, wọ́n sì lépa wọn ní gbogbo ọ̀nà títí dé Sidoni ńlá, sí Misrefoti-Maimu, àti sí àfonífojì Mispa ní ìlà-oòrùn, títí tí kò fi ku ẹnìkankan sílẹ̀.