Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Protection: Jacob

1 ẹsẹ · 57 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Jacob

  1. Angẹli tí ó dá mi ní ìdè kúrò lọ́wọ́ gbogbo ewu, kí ó súre fún àwọn ọmọkùnrin wọ̀nyí. Kí a máa fi orúkọ mi pè wọ́n àti orúkọ àwọn baba mi Abrahamu àti Isaaki, kí wọn kí ó sì pọ̀ sí i lọ́pọ̀lọ́pọ̀ lórí ilẹ̀ ayé.”