Skip to content

Merom

2 verses

33.0700, 35.6000 Wo lórí Google Maps

Àwọn ẹsẹ tí ó mẹ́nu kan Merom

  1. Gbogbo àwọn ọba yìí pa ọmọ-ogun wọn pọ̀, wọ́n sì pa ibùdó sí ibi omi Meromu láti bá Israẹli jà.

  2. Bẹ́ẹ̀ ni Joṣua àti gbogbo àwọn ọmọ-ogun rẹ̀ yọ sí wọn ní òjijì ní ibi omi Meromu, wọ́n sì kọlù wọ́n,