Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Proselytes: Later called devout Greeks

2 ẹsẹ · 14 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Later called devout Greeks

  1. Àwọn Giriki kan sì wà nínú àwọn tí ó gòkè wá láti sìn nígbà àjọ,

  2. A sì yí nínú wọn lọ́kàn padà, wọ́n sì darapọ̀ mọ́ Paulu àti Sila, bákan náà ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ nínú àwọn olùfọkànsìn Helleni àti nínú àwọn obìnrin ọlọ́lá, kì í ṣe díẹ̀.