Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Proselytes: Pharisees, zealous in making

1 ẹsẹ · 14 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Pharisees, zealous in making

  1. “Ègbé ni fún yín, ẹ̀yin olùkọ́ òfin àti Farisi, ẹ̀yin àgàbàgebè! Nítorí ẹ̀yin rin yí ilẹ̀ àti òkun ká láti yí ẹnìkan lọ́kàn padà, ṣùgbọ́n ẹ̀yin ń sọ ọ́ di ọmọ ọ̀run àpáàdì ní ìlọ́po méjì ju ẹ̀yin pàápàá.