Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Proselytes: From the Egyptians and Edomites restricted to the third generation from holding office in the congregation

2 ẹsẹ · 14 abala

Àwọn ẹsẹ nípa From the Egyptians and Edomites restricted to the third generation from holding office in the congregation

  1. Ìwọ kò gbọdọ̀ kórìíra ará Edomu kan nítorí arákùnrin rẹ ni. Ìwọ kò gbọdọ̀ kórìíra ará Ejibiti, nítorí o gbé gẹ́gẹ́ bí àjèjì ní ilẹ̀ rẹ̀.

  2. Ìran kẹta àwọn ọmọ tí a bí fún wọn lè wọ ìpéjọ Olúwa.