Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Prophecy: Blessedness of reading, hearing, and keeping

2 ẹsẹ · 47 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Blessedness of reading, hearing, and keeping

  1. Ẹni ìbùkún ni ẹni tí ń kà, àti àwọn tí ó ń gbọ́ ọ̀rọ̀ ìsọtẹ́lẹ̀ yìí, tí ó sì ń pa nǹkan wọ̀n-ọn-nì tí a kọ sínú rẹ̀ mọ́, nítorí ìgbà kù sí dẹ̀dẹ̀.

  2. “Kíyèsi i, èmi ń bọ̀ kánkán! Ìbùkún ni fún ẹni tí ń pa ọ̀rọ̀ ìsọtẹ́lẹ̀ inú ìwé yìí mọ́!”