Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Prophecy: Is for the benefit of after ages

1 ẹsẹ · 47 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Is for the benefit of after ages

  1. Àwọn ẹni tí a fihàn fún, pé kì í ṣe fún àwọn tìkára wọn, bí kò ṣe fún àwa ni wọ́n ṣe ìránṣẹ́ ohun wọ̀n-ọn-nì, tí a ti ròyìn fún yin nísinsin yìí, láti ọ̀dọ̀ àwọn tó ti ń wàásù ìyìnrere náà fún yín nípasẹ̀ Ẹ̀mí Mímọ́ tí a rán wá láti ọ̀run; ohun tí àwọn angẹli ń fẹ́ láti wò.