Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Prophecy: Publicly proclaimed
Àwọn ẹsẹ nípa Publicly proclaimed
Olúwa wí fún mi pé, “Kéde gbogbo ọ̀rọ̀ yìí ní àwọn ìlú Juda àti ní gbogbo òpópónà ìgboro Jerusalẹmu pé, ‘Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ májẹ̀mú yìí, kí ẹ sì se wọn.