Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Prisons: Sometimes entrusted the care of the prison to well-conducted prisoners

2 ẹsẹ · 44 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Sometimes entrusted the care of the prison to well-conducted prisoners

  1. Nítorí náà, alábojútó ọgbà ẹlẹ́wọ̀n fi Josẹfu ṣe alákòóso ohun gbogbo tí ó wà nínú ẹ̀wọ̀n, àti ohun tí wọn ń ṣe níbẹ̀.

  2. Wọ́dà náà kò sì mikàn nípa gbogbo ohun tí ó fi sí abẹ́ àkóso Josẹfu, nítorí pé Olúwa wà pẹ̀lú Josẹfu, ó sì ń jẹ́ kí ó ṣe àṣeyọrí nínú ohun gbogbo tí ó dáwọ́lé.