Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Prisons: Put to death if prisoners escaped
Àwọn ẹsẹ nípa Put to death if prisoners escaped
Nígbà tí Herodu sì wá a kiri, tí kò sì rí i, ó wádìí àwọn ẹ̀ṣọ́, ó pàṣẹ pé, kí a pa wọ́n. Herodu sì sọ̀kalẹ̀ láti Judea lọ sí Kesarea, ó sì wà níbẹ̀ fún ìgbà díẹ̀.