Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Prisons: Often chained to two soldiers
Àwọn ẹsẹ nípa Often chained to two soldiers
Ní òru náà gan an ti Herodu ìbá sì mú un jáde, Peteru ń sùn láàrín àwọn ọmọ-ogun méjì, a fi ẹ̀wọ̀n méjì dè é, ẹ̀ṣọ́ sí wà ní ẹnu-ọ̀nà, wọ́n ń ṣọ́ túbú náà.