Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Prisons: Strictly guarded the doors
Àwọn ẹsẹ nípa Strictly guarded the doors
Ní òru náà gan an ti Herodu ìbá sì mú un jáde, Peteru ń sùn láàrín àwọn ọmọ-ogun méjì, a fi ẹ̀wọ̀n méjì dè é, ẹ̀ṣọ́ sí wà ní ẹnu-ọ̀nà, wọ́n ń ṣọ́ túbú náà.