Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Mountains: Hor

3 ẹsẹ · 82 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Hor

  1. Gbogbo ìjọ ènìyàn Israẹli sì jáde láti Kadeṣi wọ́n sì wá sí orí òkè Hori.

  2. Fún ààlà ìhà àríwá, fa ìlà láti Òkun Ńlá lọ sí orí òkè Hori,

  3. àti láti orí òkè Hori sí Lebo-Hamati. Nígbà náà ààlà náà yóò lọ sí Sedadi,