Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Mountains: Causes, to tremble

2 ẹsẹ · 82 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Causes, to tremble

  1. Àwọn òkè ńlá wárìrì níwájú rẹ̀, àwọn òkè kéékèèké sì di yíyọ́, ilẹ̀ ayé sì jóná níwájú rẹ̀, àní ayé àti gbogbo àwọn tí ń gbé inú rẹ̀.

  2. Àwọn òkè ńlá ri ọ wọn sì wárìrì àgbàrá òjò ń sàn án kọjá lọ; ibú ń ké ramúramù ó sì gbé irú omi sókè.