Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Jebusites

41 ẹsẹ · 7 abala

Àwọn ẹsẹ Bíbélì pàtàkì

Sẹ́ nípa ìwé
  1. Nínú àwọn ìran Bani: Meṣullamu, Malluki, Adaiah, Jaṣubu, Ṣeali àti Jerimoti.

  2. Nínú àwọn Pahati-Moabu: Adma, Kelali, Benaiah, Maaseiah, Mattaniah, Besaleli, Binnui àti Manase.

  3. Nínú àwọn ìran Harimu: Elieseri, Iṣiah, Malkiah àti Ṣemaiah, Simeoni,

  4. Benjamini, Malluki àti Ṣemariah.

  5. Nínú àwọn ìran Haṣumu: Mattenai, Mattatta, Sabadi, Elifaleti, Jeremai, Manase àti Ṣimei.

  6. Nínú àwọn ìran Bani: Maadai, Amramu, Ueli,

  7. Benaiah, Bediah, Keluhi

  8. Faniah, Meremoti, Eliaṣibu,

  9. Mattaniah, Mattenai àti Jaasu.

  10. Àti Bani, àti Binnui: Ṣimei,

  11. Ṣelemiah, Natani, Adaiah,

  12. Maknadebai, Sasai, Ṣarai,

  13. Asareeli, Ṣelemiah, Ṣemariah,

  14. Ṣallumu, Amariah àti Josẹfu.

  15. Nínú àwọn ìran Nebo: Jeieli, Mattitiah, Sabadi, Sebina, Jaddai, Joẹli àti Benaiah.

  16. Gbogbo àwọn wọ̀nyí ló fẹ́ obìnrin àjèjì, àwọn mìíràn nínú wọn sì bi ọmọ ní ipasẹ̀ àwọn ìyàwó wọ̀nyí.