Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Jacob: Journeys to Ephrath; Benjamin is born to; Rachel dies, and is »buried in the way to Ephrath, which is Bethlehem«

4 ẹsẹ · 49 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Journeys to Ephrath; Benjamin is born to; Rachel dies, and is »buried in the way to Ephrath, which is Bethlehem«

  1. Nígbà náà ni wọ́n ń tẹ̀síwájú nínú ìrìnàjò wọn láti Beteli. Nígbà tí ó sì ku díẹ̀ kí wọn dé Efrata, Rakeli bẹ̀rẹ̀ sí ní rọbí, ó sì ní ìdààmú púpọ̀.

  2. Bí ó sì ti ń rọbí pẹ̀lú ìrora yìí, agbẹ̀bí wí fún un pé, “Má bẹ̀rù nítorí ọmọkùnrin mìíràn ni ó ń bọ̀ yìí.”

  3. Bí o sì ti fẹ́ gbé ẹ̀mí mi, torí pé ó ń kú lọ, ó pe ọmọ rẹ̀ náà ní Bene-Oni, ọmọ ìpọ́njú. Ṣùgbọ́n Jakọbu sọ ọmọ náà ní Benjamini, ọmọ oókan àyà mi.

  4. Báyìí ni Rakeli kú, a sì sin ín sí ọ̀nà Efrata (ti o túmọ̀ sí, Bẹtilẹhẹmu).