Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Jacob: Journeys to Shalem, where he purchases a parcel of ground from Hamor, and erects an altar
Àwọn ẹsẹ nípa Journeys to Shalem, where he purchases a parcel of ground from Hamor, and erects an altar
Lẹ́yìn ìgbà tí Jakọbu tí Padani-Aramu dé, àlàáfíà ni Jakọbu dé ìlú Ṣekemu ní ilẹ̀ Kenaani, ó sì pàgọ́ sí itòsí ìlú náà.
Ó sì ra ilẹ̀ kan tí ó pàgọ́ sí ni ọgọ́rùn-ún owó fàdákà lọ́wọ́ àwọn ọmọ Hamori tí í ṣe baba Ṣekemu.
Níbẹ̀ ni ó gbé tẹ́ pẹpẹ kan tí ó pè ní El Elohe Israẹli.