Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Jacob: Meets angels of God on the journey, and calls the place Mahanaim
Àwọn ẹsẹ nípa Meets angels of God on the journey, and calls the place Mahanaim
Jakọbu sì ń bá ọ̀nà tirẹ̀ lọ, àwọn angẹli Ọlọ́run sì pàdé rẹ̀.
Nígbà tí Jakọbu rí wọn, ó wí pé, “Àgọ́ Ọlọ́run ni èyí!” Ó sì pe orúkọ ibẹ̀ ni Mahanaimu.