Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Birds: What species were unclean

16 ẹsẹ · 107 abala

Àwọn ẹsẹ nípa What species were unclean

  1. “ ‘Àwọn ẹyẹ wọ̀nyí ni ẹ gbọdọ̀ kórìíra tí ẹ kò gbọdọ̀ jẹ wọ́n torí pé ohun ìríra ni wọ́n: idì, oríṣìíríṣìí igún,

  2. àwòdì àti onírúurú àṣá,

  3. onírúurú ẹyẹ ìwò,

  4. Òwìwí, onírúurú ògòǹgò, onírúurú ẹ̀lúùlú, onírúurú àwòdì,

  5. Òwìwí kéékèèké, onírúurú òwìwí,

  6. Òwìwí funfun àti òwìwí ilẹ̀ pápá, àti àkàlà,

  7. àkọ̀, onírúurú òòdẹ̀, atọ́ka àti àdán.

  8. “ ‘Gbogbo kòkòrò tí ń fò tí ó sì ń fi ẹsẹ̀ mẹ́rẹ̀ẹ̀rin rìn ni wọ́n jẹ́ ìríra fún yín,

  9. Ṣùgbọ́n ìwọ̀nyí ní ẹ kò gbọdọ̀ jẹ: idì, igún, àkàlà,

  10. onírúurú àṣá àti àṣá alátagbà,

  11. onírúurú ẹyẹ ìwò,

  12. ògòǹgò, òwìwí, pẹ́pẹ́yẹdò àti onírúurú àwòdì,

  13. onírúurú òwìwí,

  14. òwìwí ọ̀dàn, àkàlà, ìgò,

  15. àkọ̀, òòdẹ̀, onírúurú ẹyẹ odò mìíràn, atọ́ka àti àdán.

  16. Àti gbogbo kòkòrò tí ń fò tí wọ́n ń kọ́wọ̀ọ́ rìn jẹ́ aláìmọ́ fun un yín, ẹ má ṣe jẹ wọ́n.