Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Birds: Sparrow
Àwọn ẹsẹ nípa Sparrow
Ológoṣẹ́ méjì kọ́ ni à ń tà ní owó idẹ wẹ́wẹ́ kan? Síbẹ̀ kò sí ọ̀kan nínú wọn tí yóò ṣubú lu ilẹ̀ lẹ́yìn Baba yin.
Àti pé gbogbo irun orí yín ni a ti kà pé.
Nítorí náà, ẹ má ṣe fòyà; ẹ̀yin ní iye lórí ju ọ̀pọ̀ ológoṣẹ́ lọ.