Fò sí àkóónú

circa 1446–1406 BC

The Wilderness Years

Forty years of wandering in the desert test Israel's faith and prepare a new generation to enter the promised land.

2,247 ẹsẹ · 2 ìwé tí a bo

Àwọn ẹsẹ láti sáà yìí

Sẹ́ nípa ìwé
  1. Wọ́n kúrò ní Rimoni-Peresi wọ́n sì pàgọ́ ní Libina.

  2. Wọ́n kúrò ní Libina wọ́n sì pàgọ́ ní Rissa.

  3. Wọ́n kúrò ní Rissa wọ́n sì pàgọ́ ní Kehelata.

  4. Wọ́n kúrò ní Kehelata wọ́n sì pàgọ́ ní orí òkè Ṣeferi.

  5. Wọ́n kúrò lórí òkè Ṣeferi wọ́n sì pàgọ́ ní Harada.

  6. Wọ́n kúrò ní Harada wọ́n sì pàgọ́ ní Makhelotu.

  7. Wọ́n kúrò ní Makhelotu wọ́n sì pàgọ́ ní Tahati.

  8. Wọ́n kúrò ní Tahati wọ́n sì pàgọ́ ní Tẹra.

  9. Wọ́n kúrò ní Tẹra wọ́n sì pàgọ́ ní Mitka.

  10. Wọ́n kúrò ní Mitka wọ́n pàgọ́ ní Haṣmona.

  11. Wọ́n kúrò ní Haṣmona wọ́n sì pàgọ́ ní Moserotu.

  12. Wọ́n kúrò ní Moserotu wọ́n sì pàgọ́ ní Bene-Jaakani.

  13. Wọ́n kúrò ní Bene-Jaakani wọ́n sì pàgọ́ ní Hori-Haggidgadi.

  14. Wọ́n kúrò ní Hori-Haggidgadi wọ́n sí pàgọ́ ní Jotbata.

  15. Wọ́n kúrò ní Jotbata wọ́n sì pàgọ́ ní Abrona.

  16. Wọ́n kúrò ní Abrona wọ́n sì pàgọ́ ní Esioni-Geberi.

  17. Wọ́n kúrò ní Esioni-Geberi wọ́n sì pàgọ́ ní Kadeṣi nínú aginjù Sini.

  18. Wọ́n kúrò ní Kadeṣi wọ́n sì pàgọ́ ní orí òkè Hori, lẹ́bàá Edomu.

  19. Nípa àṣẹ Olúwa, Aaroni àlùfáà gùn orí òkè Hori, níbẹ̀ ni ó kú. Ní ọjọ́ kìn-ín-ní oṣù karùn-ún, ọdún ogójì, lẹ́yìn tí àwọn ọmọ Israẹli ti ilẹ̀ Ejibiti jáde wá.

  20. Aaroni jẹ́ ẹni ọgọ́fà ọdún ó lé mẹ́ta (123) ní ìgbà tí ó kú sí orí òkè Hori.

  21. Àwọn ará Kenaani, ọba Aradi, tí ń gbé ìhà gúúsù ní ilẹ̀ Kenaani gbọ́ pé àwọn ọmọ Israẹli ń bọ̀.

  22. Wọ́n kúrò ní orí òkè Hori, wọ́n sì pàgọ́ ní Salmona.

  23. Wọ́n kúrò ní Salmona wọ́n sì pàgọ́ ní Punoni.

  24. Wọ́n kúrò ní Punoni wọ́n sì pàgọ́ ní Obotu.

  25. Wọ́n kúrò ní Obotu wọ́n sì pàgọ́ ní Iye-Abarimu, ní agbègbè Moabu.