Skip to content

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Water: Streams

2 ẹsẹ · 84 abala

Àwọn ẹsẹ nípa Streams

  1. Ó mú ìṣàn omi jáde láti inú àpáta omi ṣíṣàn sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí odò.

  2. Nígbà náà ni àwọn arọ yóò máa fò bí àgbọ̀nrín, àti ahọ́n odi yóò ké fún ayọ̀. Odò yóò tú jáde nínú aginjù àti àwọn odò nínú aṣálẹ̀.