Fò sí àkóónú

Àwọn ẹsẹ Bíbélì nípa Water: (Covering the sea,) of the general diffusion of the knowledge of God

2 ẹsẹ · 84 abala

Àwọn ẹsẹ nípa (Covering the sea,) of the general diffusion of the knowledge of God

  1. Wọn kò ní ṣe ni léṣe tàbí pa ni run ní gbogbo òkè mímọ́ mi, nítorí gbogbo ayé yóò kún fún ìmọ̀ Olúwa gẹ́gẹ́ bí omi ti bo Òkun.

  2. Nítorí tí ayé yóò kún fún ìmọ̀ ògo Olúwa, bí omi ti bo Òkun.